Àwọn Ọba Kinni 22:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoṣafati ọba kan àwọn ọkọ̀ ojú omi bíi ti ìlú Taṣiṣi, láti kó wọn lọ sí ilẹ̀ Ofiri láti lọ wá wúrà. Ṣugbọn wọn kò lè lọ nítorí pé àwọn ọkọ̀ náà bàjẹ́ ní Esiongeberi.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:45-53