Àwọn Ọba Kinni 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu bá pada lọ sílé pẹlu ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ati ibinu, nítorí ohun tí Naboti ará Jesireeli wí fún un. Ó dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀, ó kọjú sí ògiri, kò sì jẹun.

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:3-5