Àwọn Ọba Kinni 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Naboti dáhùn pé, “Ọwọ́ àwọn baba ńlá mi ni mo ti jogún ọgbà àjàrà yìí; OLUWA má jẹ́ kí n rí ohun tí n óo fi gbé e fún ọ.”

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:1-10