Àwọn Ọba Kinni 21:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesebẹli, aya rẹ̀, wọlé tọ̀ ọ́ lọ, ó sì bi í pé, “Kí ló dé tí ọkàn rẹ fi rẹ̀wẹ̀sì tóbẹ́ẹ̀ tí o kò fi jẹun?”

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:1-9