Àwọn Ọba Kinni 21:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kéde ọjọ́ ààwẹ̀ kan, wọ́n pe àwọn eniyan jọ, wọ́n sì fún Naboti ní ipò ọlá láàrin wọn.

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:7-22