Àwọn Ọba Kinni 21:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyankeniyan meji tí wọ́n ya aṣa yìí jókòó níwájú rẹ̀, wọ́n sì purọ́ mọ́ ọn lójú gbogbo eniyan pé ó bú Ọlọrun ati ọba. Wọ́n bá fà á jáde sẹ́yìn odi ìlú, wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta pa.

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:8-15