Àwọn Ọba Kinni 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà ati àwọn eniyan ńláńlá tí wọn ń gbé ìlú náà ṣe bí Jesebẹli ti ní kí wọ́n ṣe ninu ìwé tí ó kọ ranṣẹ sí wọn.

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:2-19