Àwọn Ọba Kinni 20:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii náà sáré tu aṣọ tí ó fi wé ojú, lẹsẹkẹsẹ ọba sì mọ̀ pé ọ̀kan ninu àwọn wolii ni.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:35-43