Àwọn Ọba Kinni 20:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii náà bá wí fún ọba pé, “OLUWA ní, nítorí pé o jẹ́ kí ẹni tí mo ti pinnu láti pa sá lọ, ẹ̀mí rẹ ni n óo fi dípò ẹ̀mí rẹ̀, n óo sì pa àwọn eniyan rẹ dípò àwọn eniyan rẹ̀.”

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:34-43