Àwọn Ọba Kinni 20:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn níbi tí mo ti ń lọ sókè sódò, tí mò ń ṣe àwọn nǹkan mìíràn, ọkunrin yìí sá lọ.”Ọba dá a lóhùn pé, “Ìwọ náà ti dá ara rẹ lẹ́jọ́, bẹ́ẹ̀ gan-an ni yóo sì rí.”

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:33-43