Àwọn Ọba Kinni 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii náà tún tọ Ahabu ọba lọ, ó wí fún un pé, “Pada lọ kó àwọn ọmọ ogun rẹ jọ, kí o sì ṣètò dáradára; nítorí pé, ọba Siria yóo tún bá ọ jagun ní ìbẹ̀rẹ̀ àkókò òjò.”

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:13-26