Àwọn Ọba Kinni 20:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu ọba bá lọ sójú ogun, ó kó ọpọlọpọ ẹṣin ati kẹ̀kẹ́ ogun; ó ṣẹgun àwọn ọmọ ogun Siria, ó sì pa ọpọlọpọ ninu wọn.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:16-27