Àwọn Ọba Kinni 20:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku wọn pa ẹni tí ó dojú ìjà kọ. Àwọn ọmọ ogun Siria bá sá. Àwọn ọmọ ogun Israẹli sì ń lé wọn lọ. Ṣugbọn Benhadadi, ọba Siria, ti gun ẹṣin sá lọ, pẹlu àwọn jagunjagun tí wọ́n gun ẹṣin.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:18-21