Àwọn Ọba Kinni 20:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ogun ṣe jáde ní ìlú: àwọn ọ̀dọ́ ọmọ ogun ni wọ́n ṣáájú ogun, lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ ogun Israẹli tẹ̀lé wọn.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:10-22