Àwọn Ọba Kinni 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn oníṣẹ́ Benhadadi ọba wí fún un pé, “Oriṣa orí òkè ni oriṣa àwọn ọmọ Israẹli. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ṣẹgun wa. Ṣugbọn bí a bá gbógun tì wọ́n ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, a óo ṣẹgun wọn.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:21-32