Àwọn Ọba Kinni 2:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ tí o bá jáde kọjá odò Kidironi, pípa ni n óo pa ọ́, ẹ̀jẹ̀ rẹ yóo sì wà lórí ara rẹ.”

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:31-42