Àwọn Ọba Kinni 2:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọba ranṣẹ pe Ṣimei, ó wí fún un pé, “Kọ́ ilé kan sí Jerusalẹmu níhìn-ín kí o sì máa gbé ibẹ̀. O kò gbọdọ̀ jáde lọ sí ibìkankan.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:30-44