Àwọn Ọba Kinni 2:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba fi Bẹnaya jẹ balogun rẹ̀ dípò Joabu, ó sì fi Sadoku jẹ alufaa dípò Abiatari.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:33-36