Àwọn Ọba Kinni 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹnaya ọmọ Jehoiada bá lọ sinu Àgọ́ OLUWA, ó pa Joabu, wọn sì sin ín sinu ilé rẹ̀ ninu aṣálẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:28-44