Àwọn Ọba Kinni 2:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣimei dá a lóhùn, ó ní, “Gbogbo ohun tí o sọ ni ó dára, oluwa mi, bí o ti wí ni èmi iranṣẹ rẹ yóo sì ṣe.” Ṣimei sì wà ní Jerusalẹmu fún ìgbà pípẹ́.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:36-45