Àwọn Ọba Kinni 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe àdéhùn ibi tí olukuluku yóo lọ wò ní gbogbo ilẹ̀ náà, olukuluku sì gba ọ̀nà tirẹ̀ lọ. Ahabu ọba lọ sí apá kan, Ọbadaya sì lọ sí apá keji.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:1-8