Àwọn Ọba Kinni 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu sọ fún Ọbadaya pé, “Lọ wo gbogbo orísun omi ati àfonífojì ní gbogbo ilẹ̀ yìí, kí o wò ó bóyá a lè rí koríko láti fi bọ́ àwọn ẹṣin ati àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, kí wọ́n má baà kú.”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:1-7