Àwọn Ọba Kinni 18:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesebẹli bẹ̀rẹ̀ sí pa àwọn wolii OLUWA, Ọbadaya yìí ló kó ọgọrun-un ninu wọn pamọ́ sinu ihò àpáta meji, ó kó aadọta sinu ihò kọ̀ọ̀kan, ó sì ń fún wọn ní oúnjẹ ati omi.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:1-12