Àwọn Ọba Kinni 18:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Ọbadaya ti ń lọ, lójijì ni ó pàdé Elija. Ó ranti rẹ̀, ó dojúbolẹ̀, ó kí i tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀, ó sì bi í léèrè pé, “Àbí ìwọ kọ́ ni, Elija, oluwa mi?”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:1-12