Àwọn Ọba Kinni 18:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó òkúta mejila jọ, òkúta kọ̀ọ̀kan dúró fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Jakọbu, ẹni tí OLUWA sọ fún pé, “Israẹli ni orúkọ rẹ yóo máa jẹ́.”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:29-34