Àwọn Ọba Kinni 18:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi òkúta mejeejila náà kọ́ pẹpẹ ní orúkọ OLUWA. Ó gbẹ́ kòtò kan yí pẹpẹ náà ká, kòtò náà tóbi tó láti gba òṣùnwọ̀n irúgbìn meji (nǹkan bíi lita mẹrinla).

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:26-40