Àwọn Ọba Kinni 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tó yá, Elija wí fún gbogbo àwọn eniyan náà pé, “Ẹ súnmọ́ mi níhìn-ín.” Gbogbo wọn súnmọ́ ọn, wọ́n sì yí i ká. Ó bá tún pẹpẹ OLUWA tí ó ti wó ṣe.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:24-40