Àwọn Ọba Kinni 18:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọ̀sán pọ́n, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí kígbe, wọ́n ń sáré kiri bíi wèrè, títí tí ó fi di àkókò ìrúbọ ọ̀sán, ṣugbọn Baali kò dá wọn lóhùn rárá. Kò tilẹ̀ fọhùn.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:22-32