Àwọn Ọba Kinni 17:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó képe OLUWA, ó ní, “OLUWA, Ọlọrun mi, kí ló dé tí o fi jẹ́ kí irú ìdààmú yìí bá obinrin opó tí mò ń gbé ọ̀dọ̀ rẹ̀ yìí, tí o jẹ́ kí ọmọ rẹ̀ kú?”

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:15-23