Àwọn Ọba Kinni 17:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija bá na ara rẹ̀ sórí ọmọ yìí nígbà mẹta, ó sì ké pe OLÚWA, ó ní, “OLUWA Ọlọrun mi, jẹ́ kí ẹ̀mí ọmọ yìí tún pada sinu rẹ̀.”

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:13-24