Àwọn Ọba Kinni 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija dáhùn pé, “Gbé ọmọ náà fún mi.” Ó bá gba òkú ọmọ náà lọ́wọ́ rẹ̀, ó gbé e gun orí òkè ilé lọ sinu yàrá tí ó ń gbé, ó sì tẹ́ ẹ sórí ibùsùn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:11-24