Àwọn Ọba Kinni 17:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin yìí bá lọ, ó ṣe bí Elija ti wí. Òun ati Elija ati gbogbo ará ilé rẹ̀ sì ń jẹ àjẹyó fún ọpọlọpọ ọjọ́.

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:12-22