Àwọn Ọba Kinni 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyẹ̀fun kò tán ninu ìkòkò rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kólòbó òróró rẹ̀ kò sì gbẹ, bí OLUWA ti ṣèlérí fún un láti ẹnu Elija.

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:11-22