Àwọn Ọba Kinni 15:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún keji tí Asa jọba ní Juda, ni Nadabu, ọmọ Jeroboamu, gorí oyè ní ilẹ̀ Israẹli, ó sì jọba fún ọdún meji.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:19-31