Àwọn Ọba Kinni 15:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, ó tẹ̀lé ọ̀nà baba rẹ̀, ó sì dá irú ẹ̀ṣẹ̀ tí baba rẹ̀ mú kí Israẹli dá.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:16-28