Àwọn Ọba Kinni 15:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Asa jáde láyé, wọ́n sì sin ín sí ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi. Jehoṣafati, ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:21-33