Àwọn Ọba Kinni 14:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu jáde láyé, wọ́n sì sin ín sinu ibojì ọba, ní ìlú Dafidi. Naama ará Amoni ni ìyá rẹ̀. Abijamu ọmọ rẹ̀ ni ó sì gun orí oyè lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:27-31