Àwọn Ọba Kinni 14:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo ìgbà ayé Rehoboamu ati ti Jeroboamu ni àwọn mejeeji í máa gbógun ti ara wọn.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:26-31