Àwọn Ọba Kinni 14:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn nǹkan yòókù tí Rehoboamu ọba ṣe ni a kọ sílẹ̀ ninu Ìwé Ìtàn Àwọn Ọba Juda.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:19-30