Àwọn Ọba Kinni 14:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbàkúùgbà tí ọba bá ń lọ sinu ilé OLUWA, àwọn ẹ̀ṣọ́ á gbé apata náà tẹ̀lé e, wọn á sì dá wọn pada sinu ilé ìṣúra lọ́dọ̀ àwọn ẹ̀ṣọ́.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:23-31