Àwọn Ọba Kinni 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejidinlogun tí Jeroboamu jọba Israẹli, ni Abijamu gorí oyè ní ilẹ̀ Juda.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:1-9