Àwọn Ọba Kinni 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu bá dá wọn lóhùn pé, “Ẹ máa lọ ná, lẹ́yìn ọjọ́ mẹta, ẹ pada wá gbọ́ èsì.” Àwọn eniyan náà bá pada lọ.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:1-11