Àwọn Ọba Kinni 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu ọba bá lọ jíròrò pẹlu àwọn àgbààgbà tí wọ́n jẹ́ olùdámọ̀ràn Solomoni baba rẹ̀ nígbà ayé rẹ̀, ó bi wọ́n léèrè pé, “Irú ìdáhùn wo ni ó yẹ kí n fún àwọn eniyan wọnyi?”

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:1-7