Àwọn Ọba Kinni 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àjàgà wúwo ni Solomoni baba rẹ gbé bọ̀ wá lọ́rùn. Ṣugbọn bí o bá dín iṣẹ́ líle baba rẹ yìí kù, tí o sì mú kí ìgbé ayé rọ̀ wá lọ́rùn, a óo máa sìn ọ́.”

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:1-13