Àwọn Ọba Kinni 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu lọ sí Ṣekemu, nítorí pé gbogbo Israẹli ti péjọ níbẹ̀ láti fi jọba.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:1-4