Àwọn Ọba Kinni 11:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó kú, wọ́n sin ín sí ìlú Dafidi, baba rẹ̀, Rehoboamu, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:41-43