Àwọn Ọba Kinni 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jeroboamu ọmọ Nebati gbọ́ ìròyìn yìí ní Ijipti, (níbẹ̀ ni ó ń gbé láti ìgbà tí ó ti sá lọ fún Solomoni ọba), ó pada wá sílé láti Ijipti.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:1-11