Àwọn Ọba Kinni 11:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn nǹkan yòókù tí Solomoni ṣe: gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, ati ọgbọ́n rẹ̀, ni a kọ sinu Ìwé Ìṣe Solomoni.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:32-43