Àwọn Ọba Kinni 11:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọ̀rọ̀ yìí, Solomoni ń wá ọ̀nà láti pa Jeroboamu, ṣugbọn Jeroboamu sá lọ sọ́dọ̀ Ṣiṣaki, ọba Ijipti, níbẹ̀ ni ó sì wà títí tí Solomoni fi kú.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:39-43