Àwọn Ọba Kinni 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Solomoni di àgbàlagbà, àwọn iyawo rẹ̀ mú kí ọkàn rẹ̀ ṣí kúrò lọ́dọ̀ OLUWA, ó ń bọ àwọn oriṣa àjèjì, kò sì ṣe olóòótọ́ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀ mọ́, bíi Dafidi, baba rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:2-9